Máàkù 12:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ó wá jókòó síbi tó ti ń rí àwọn àpótí ìṣúra ní ọ̀ọ́kán,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í wo bí àwọn èrò ṣe ń fi owó sínú àwọn àpótí ìṣúra náà, ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀ sì ń fi ẹyọ owó púpọ̀ síbẹ̀.+
41 Ó wá jókòó síbi tó ti ń rí àwọn àpótí ìṣúra ní ọ̀ọ́kán,+ ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í wo bí àwọn èrò ṣe ń fi owó sínú àwọn àpótí ìṣúra náà, ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀ sì ń fi ẹyọ owó púpọ̀ síbẹ̀.+