ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà yẹn, Jòhánù+ Arinibọmi wá, ó ń wàásù+ ní aginjù Jùdíà,

  • Mátíù 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Òun gangan ni ẹni tí wòlíì Àìsáyà+ sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ pé: “Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: ‘Ẹ ṣètò ọ̀nà Jèhófà!* Ẹ mú àwọn ọ̀nà rẹ̀ tọ́.’”+

  • Máàkù 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: ‘Ẹ ṣètò ọ̀nà Jèhófà!* Ẹ mú àwọn ọ̀nà rẹ̀ tọ́.’”+

  • Lúùkù 1:67
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 67 Ẹ̀mí mímọ́ wá kún inú Sekaráyà bàbá rẹ̀, ó sì sọ tẹ́lẹ̀, ó ní:

  • Lúùkù 1:76
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 76 Àmọ́ ní tìrẹ, ọmọ kékeré, wòlíì Ẹni Gíga Jù Lọ la ó máa pè ọ́, torí o máa lọ níwájú Jèhófà* láti múra àwọn ọ̀nà rẹ̀ sílẹ̀,+

  • Lúùkù 3:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ó wá lọ sí gbogbo ìgbèríko tó yí Jọ́dánì ká, ó ń wàásù pé kí àwọn èèyàn ṣèrìbọmi láti fi hàn pé wọ́n ti ronú pìwà dà, kí wọ́n lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà,+ 4 bí a ṣe kọ ọ́ sínú ìwé ọ̀rọ̀ wòlíì Àìsáyà pé: “Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: ‘Ẹ ṣètò ọ̀nà Jèhófà!* Ẹ mú àwọn ọ̀nà rẹ̀ tọ́.+

  • Lúùkù 7:27, 28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ẹni yìí la kọ̀wé nípa rẹ̀ pé: ‘Wò ó! Màá rán ìránṣẹ́ mi ṣáájú rẹ,* ẹni tó máa ṣètò ọ̀nà rẹ dè ọ́.’+ 28 Mò ń sọ fún yín, nínú àwọn tí obìnrin bí, kò sí ẹni tó tóbi ju Jòhánù lọ, àmọ́ ẹni kékeré nínú Ìjọba Ọlọ́run tóbi jù ú lọ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́