-
1 Jòhánù 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Gbogbo ẹni tó bá gbà gbọ́ pé Jésù ni Kristi ni a ti bí látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ gbogbo ẹni tó bá sì nífẹ̀ẹ́ ẹni tó jẹ́ ká bí ẹnì kan, máa nífẹ̀ẹ́ ẹni tí onítọ̀hún bí.
-