Máàkù 8:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó wá fa ọkùnrin afọ́jú náà lọ́wọ́ jáde sẹ́yìn abúlé náà. Lẹ́yìn tó tutọ́ sí ojú rẹ̀,+ ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, ó sì bi í pé: “Ṣé o rí nǹkan kan?”
23 Ó wá fa ọkùnrin afọ́jú náà lọ́wọ́ jáde sẹ́yìn abúlé náà. Lẹ́yìn tó tutọ́ sí ojú rẹ̀,+ ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, ó sì bi í pé: “Ṣé o rí nǹkan kan?”