Sáàmù 34:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú Jèhófà wà lára àwọn olódodo,+Etí rẹ̀ sì ṣí sí igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́.+ Òwe 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jèhófà jìnnà réré sí àwọn ẹni burúkú,Àmọ́ ó máa ń gbọ́ àdúrà àwọn olódodo.+