Mátíù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn wòlíì èké+ tó ń wá sọ́dọ̀ yín nínú àwọ̀ àgùntàn,+ àmọ́ tó jẹ́ pé ọ̀yánnú ìkookò ni wọ́n ní inú.+
15 “Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn wòlíì èké+ tó ń wá sọ́dọ̀ yín nínú àwọ̀ àgùntàn,+ àmọ́ tó jẹ́ pé ọ̀yánnú ìkookò ni wọ́n ní inú.+