-
Jòhánù 21:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó sọ fún un lẹ́ẹ̀kẹta pé: “Símónì ọmọ Jòhánù, ṣé o ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún mi?” Ẹ̀dùn ọkàn bá Pétérù torí ó bi í lẹ́ẹ̀kẹta pé: “Ṣé o ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún mi?” Torí náà, ó sọ fún un pé: “Olúwa, o mọ ohun gbogbo; o mọ̀ pé mo ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ọ.” Jésù sọ fún un pé: “Máa bọ́ àwọn àgùntàn mi kéékèèké.+
-