Jòhánù 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 (Jòhánù jẹ́rìí nípa rẹ̀, àní, ó ké jáde pé: “Ẹni yìí ni mo sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi ti lọ níwájú mi, torí ó ti wà ṣáájú mi.’”)+
15 (Jòhánù jẹ́rìí nípa rẹ̀, àní, ó ké jáde pé: “Ẹni yìí ni mo sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi ti lọ níwájú mi, torí ó ti wà ṣáájú mi.’”)+