Ìṣe 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà tí ọkùnrin náà ṣì di Pétérù àti Jòhánù mú, gbogbo èèyàn sáré lọ bá wọn níbi tí wọ́n ń pè ní Ọ̀dẹ̀dẹ̀* Sólómọ́nì,+ ẹnu yà wọ́n gidigidi.
11 Nígbà tí ọkùnrin náà ṣì di Pétérù àti Jòhánù mú, gbogbo èèyàn sáré lọ bá wọn níbi tí wọ́n ń pè ní Ọ̀dẹ̀dẹ̀* Sólómọ́nì,+ ẹnu yà wọ́n gidigidi.