Jòhánù 5:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àmọ́ mo ní ẹ̀rí tó tóbi ju ti Jòhánù lọ, torí àwọn iṣẹ́ tí Baba mi yàn fún mi pé kí n ṣe, àwọn iṣẹ́ tí mò ń ṣe yìí, ń jẹ́rìí sí i pé Baba ló rán mi.+
36 Àmọ́ mo ní ẹ̀rí tó tóbi ju ti Jòhánù lọ, torí àwọn iṣẹ́ tí Baba mi yàn fún mi pé kí n ṣe, àwọn iṣẹ́ tí mò ń ṣe yìí, ń jẹ́rìí sí i pé Baba ló rán mi.+