Lúùkù 10:38, 39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Bí wọ́n ṣe ń lọ, ó wọ abúlé kan. Ibí ni obìnrin kan tó ń jẹ́ Màtá+ ti gbà á lálejò sínú ilé rẹ̀. 39 Ó tún ní arábìnrin kan tó ń jẹ́ Màríà, ẹni tó jókòó síbi ẹsẹ̀ Olúwa, tó sì ń fetí sí ohun tó ń sọ.*
38 Bí wọ́n ṣe ń lọ, ó wọ abúlé kan. Ibí ni obìnrin kan tó ń jẹ́ Màtá+ ti gbà á lálejò sínú ilé rẹ̀. 39 Ó tún ní arábìnrin kan tó ń jẹ́ Màríà, ẹni tó jókòó síbi ẹsẹ̀ Olúwa, tó sì ń fetí sí ohun tó ń sọ.*