ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 12:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó ti ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì níwájú wọn, wọn ò ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀,

  • Ìṣe 4:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Torí náà, wọ́n pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n jáde síta gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í fikùn lukùn, 16 wọ́n sọ pé: “Kí ni ká ṣe sọ́rọ̀ àwọn ọkùnrin yìí?+ Nítorí, ká sòótọ́, wọ́n ti ṣe iṣẹ́ àmì tó gbàfiyèsí, ó sì ṣe kedere sí gbogbo àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù,+ a ò sì lè sọ pé kò ṣẹlẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́