Jòhánù 11:43, 44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Nígbà tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó gbóhùn sókè, ó sọ pé: “Lásárù, jáde wá!”+ 44 Ọkùnrin tó ti kú náà jáde wá, tòun ti aṣọ tí wọ́n fi dì í tọwọ́tẹsẹ̀ àti aṣọ tí wọ́n fi di ojú rẹ̀. Jésù sì sọ fún wọn pé: “Ẹ tú u, kí ẹ jẹ́ kó máa lọ.”
43 Nígbà tó sọ àwọn nǹkan yìí, ó gbóhùn sókè, ó sọ pé: “Lásárù, jáde wá!”+ 44 Ọkùnrin tó ti kú náà jáde wá, tòun ti aṣọ tí wọ́n fi dì í tọwọ́tẹsẹ̀ àti aṣọ tí wọ́n fi di ojú rẹ̀. Jésù sì sọ fún wọn pé: “Ẹ tú u, kí ẹ jẹ́ kó máa lọ.”