Mátíù 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n mú kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà àti ọmọ rẹ̀ wá, wọ́n tẹ́ aṣọ àwọ̀lékè wọn sórí wọn, ó sì jókòó sórí wọn.+ Máàkù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n mú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́+ náà wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n tẹ́ aṣọ àwọ̀lékè wọn sórí rẹ̀, ó sì jókòó sórí rẹ̀.+ Lúùkù 19:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Wọ́n wá mú un lọ sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n ju aṣọ àwọ̀lékè wọn sórí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà, wọ́n sì mú kí Jésù jókòó sórí rẹ̀.+
7 Wọ́n mú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́+ náà wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n tẹ́ aṣọ àwọ̀lékè wọn sórí rẹ̀, ó sì jókòó sórí rẹ̀.+
35 Wọ́n wá mú un lọ sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n ju aṣọ àwọ̀lékè wọn sórí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà, wọ́n sì mú kí Jésù jókòó sórí rẹ̀.+