Mátíù 26:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nígbà tó di ìrọ̀lẹ́,+ òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn méjìlá (12) jókòó* sídìí tábìlì.+