Ìṣe 2:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ọlọ́run jí Jésù yìí dìde, gbogbo wa sì jẹ́rìí sí i.+ 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.
32 Ọlọ́run jí Jésù yìí dìde, gbogbo wa sì jẹ́rìí sí i.+ 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.