Ìṣe 10:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ọlọ́run jí ẹni yìí dìde ní ọjọ́ kẹta,+ ó sì jẹ́ kó fara hàn kedere,* 41 kì í ṣe fún gbogbo èèyàn, bí kò ṣe fún àwọn ẹlẹ́rìí tí Ọlọ́run ti yàn ṣáájú, fún àwa, tí a bá a jẹ, tí a sì bá a mu lẹ́yìn tí ó dìde kúrò nínú ikú.+
40 Ọlọ́run jí ẹni yìí dìde ní ọjọ́ kẹta,+ ó sì jẹ́ kó fara hàn kedere,* 41 kì í ṣe fún gbogbo èèyàn, bí kò ṣe fún àwọn ẹlẹ́rìí tí Ọlọ́run ti yàn ṣáájú, fún àwa, tí a bá a jẹ, tí a sì bá a mu lẹ́yìn tí ó dìde kúrò nínú ikú.+