Jòhánù 6:56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 Ẹnikẹ́ni tó bá ń jẹ ẹran ara mi, tó sì ń mu ẹ̀jẹ̀ mi wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, èmi náà sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀.+ 1 Kọ́ríńtì 12:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní báyìí, ẹ̀yin jẹ́ ara Kristi,+ kálukú yín sì jẹ́ ẹ̀yà ara.+ Éfésù 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni gbogbo ara+ ti para pọ̀ di ọ̀kan, tí a sì mú kí wọ́n fọwọ́ sowọ́ pọ̀ nípasẹ̀ gbogbo oríkèé tó ń pèsè ohun tí a nílò. Tí ẹ̀yà ara kọ̀ọ̀kan bá ń ṣiṣẹ́ bó ṣe yẹ, èyí á mú kí ara máa dàgbà sí i bó ṣe ń gbé ara rẹ̀ ró nínú ìfẹ́.+
56 Ẹnikẹ́ni tó bá ń jẹ ẹran ara mi, tó sì ń mu ẹ̀jẹ̀ mi wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, èmi náà sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀.+
16 Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni gbogbo ara+ ti para pọ̀ di ọ̀kan, tí a sì mú kí wọ́n fọwọ́ sowọ́ pọ̀ nípasẹ̀ gbogbo oríkèé tó ń pèsè ohun tí a nílò. Tí ẹ̀yà ara kọ̀ọ̀kan bá ń ṣiṣẹ́ bó ṣe yẹ, èyí á mú kí ara máa dàgbà sí i bó ṣe ń gbé ara rẹ̀ ró nínú ìfẹ́.+