-
Jòhánù 5:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 kí gbogbo ẹ̀dá lè máa bọlá fún Ọmọ bí wọ́n ṣe ń bọlá fún Baba. Ẹnikẹ́ni tí kò bá bọlá fún Ọmọ, kò bọlá fún Baba tó rán an.+