Jòhánù 14:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá béèrè lọ́wọ́ Baba, ó sì máa fún yín ní olùrànlọ́wọ́* míì tó máa wà pẹ̀lú yín títí láé,+ Jòhánù 14:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àmọ́ olùrànlọ́wọ́ náà, ẹ̀mí mímọ́, tí Baba máa rán ní orúkọ mi, máa kọ́ yín ní gbogbo nǹkan, ó sì máa rán yín létí gbogbo ohun tí mo sọ fún yín.+ Jòhánù 15:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà tí olùrànlọ́wọ́ tí màá rán sí yín látọ̀dọ̀ Baba bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ tó wá látọ̀dọ̀ Baba, ó máa jẹ́rìí nípa mi;+ Ìṣe 2:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ọlọ́run jí Jésù yìí dìde, gbogbo wa sì jẹ́rìí sí i.+ 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.
26 Àmọ́ olùrànlọ́wọ́ náà, ẹ̀mí mímọ́, tí Baba máa rán ní orúkọ mi, máa kọ́ yín ní gbogbo nǹkan, ó sì máa rán yín létí gbogbo ohun tí mo sọ fún yín.+
26 Nígbà tí olùrànlọ́wọ́ tí màá rán sí yín látọ̀dọ̀ Baba bá dé, ẹ̀mí òtítọ́,+ tó wá látọ̀dọ̀ Baba, ó máa jẹ́rìí nípa mi;+
32 Ọlọ́run jí Jésù yìí dìde, gbogbo wa sì jẹ́rìí sí i.+ 33 Tóò, nítorí pé a gbé e ga sí ọwọ́ ọ̀tún Ọlọ́run,+ tí ó sì gba ẹ̀mí mímọ́ tí Baba ṣèlérí,+ ó tú ohun tí ẹ rí, tí ẹ sì gbọ́ jáde.