ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Kí ẹ máa rántí ọjọ́ yìí, kí ẹ sì máa ṣe ayẹyẹ rẹ̀, kó jẹ́ àjọyọ̀ sí Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín. Ẹ máa pa àjọyọ̀ náà mọ́, ó ti di òfin fún yín títí láé.

  • Nọ́ńbà 28:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “‘Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní ni kó jẹ́ ọjọ́ Ìrékọjá+ sí Jèhófà.

  • Diutarónómì 16:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Máa rántí oṣù Ábíbù,* kí o sì máa ṣe ayẹyẹ Ìrékọjá fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ torí pé oṣù Ábíbù ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ mú ọ kúrò ní Íjíbítì ní òru.+

  • Jòhánù 11:55
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 55 Ìrékọjá+ àwọn Júù ti sún mọ́lé, ọ̀pọ̀ èèyàn láti ìgbèríko sì gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù kó tó dìgbà Ìrékọjá kí wọ́n lè wẹ ara wọn mọ́ bí Òfin ṣe sọ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́