Jòhánù 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, Ọ̀rọ̀ náà+ wà, Ọ̀rọ̀ náà sì wà pẹ̀lú Ọlọ́run,+ Ọ̀rọ̀ náà sì jẹ́ ọlọ́run kan.*+ Jòhánù 8:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Jésù sọ fún wọn pé: “Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, kí Ábúráhámù tó wà, èmi ti wà.”+ Kólósè 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Òun ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò lè rí,+ àkọ́bí nínú gbogbo ẹ̀dá; +