Jòhánù 20:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Àlàáfíà fún yín o.+ Bí Baba ṣe rán mi gẹ́lẹ́+ ni èmi náà ń rán yín.”+