Jòhánù 11:49, 50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Àmọ́ ọ̀kan lára wọn, Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ nǹkan kan rárá, 50 ẹ ò sì rò ó pé ó máa ṣe yín láǹfààní pé kí ọkùnrin kan kú torí àwọn èèyàn dípò kí gbogbo orílẹ̀-èdè pa run.”
49 Àmọ́ ọ̀kan lára wọn, Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ nǹkan kan rárá, 50 ẹ ò sì rò ó pé ó máa ṣe yín láǹfààní pé kí ọkùnrin kan kú torí àwọn èèyàn dípò kí gbogbo orílẹ̀-èdè pa run.”