Mátíù 26:57 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Àwọn tó mú Jésù wá mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà, níbi tí àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà kóra jọ sí.+
57 Àwọn tó mú Jésù wá mú un lọ sọ́dọ̀ Káyáfà+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà, níbi tí àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn àgbààgbà kóra jọ sí.+