Jòhánù 18:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Pílátù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin fúnra yín ẹ mú un, kí ẹ sì fi òfin yín dá a lẹ́jọ́.”+ Àwọn Júù sọ fún un pé: “Kò bófin mu fún wa láti pa ẹnikẹ́ni.”+
31 Pílátù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin fúnra yín ẹ mú un, kí ẹ sì fi òfin yín dá a lẹ́jọ́.”+ Àwọn Júù sọ fún un pé: “Kò bófin mu fún wa láti pa ẹnikẹ́ni.”+