Jòhánù 7:50, 51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Nikodémù, ẹni tó ti wá sọ́dọ̀ rẹ̀ tẹ́lẹ̀, tó sì wà lára wọn, sọ fún wọn pé: 51 “Òfin wa kì í ṣèdájọ́ èèyàn láìjẹ́ pé ó kọ́kọ́ gbọ́ tẹnu rẹ̀, kó sì mọ ohun tó ń ṣe, àbí ó máa ń ṣe bẹ́ẹ̀?”+ Jòhánù 19:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Nikodémù+ náà wá, ọkùnrin tó ti kọ́kọ́ wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ní òru, ó mú àdàpọ̀* òjíá àti álóé wá, ó tó nǹkan bí ọgọ́rùn-ún (100) ìwọ̀n pọ́n-ùn.*+
50 Nikodémù, ẹni tó ti wá sọ́dọ̀ rẹ̀ tẹ́lẹ̀, tó sì wà lára wọn, sọ fún wọn pé: 51 “Òfin wa kì í ṣèdájọ́ èèyàn láìjẹ́ pé ó kọ́kọ́ gbọ́ tẹnu rẹ̀, kó sì mọ ohun tó ń ṣe, àbí ó máa ń ṣe bẹ́ẹ̀?”+
39 Nikodémù+ náà wá, ọkùnrin tó ti kọ́kọ́ wá sọ́dọ̀ rẹ̀ ní òru, ó mú àdàpọ̀* òjíá àti álóé wá, ó tó nǹkan bí ọgọ́rùn-ún (100) ìwọ̀n pọ́n-ùn.*+