-
Jòhánù 14:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ẹ gbà mí gbọ́ pé mo wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba, Baba sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi; tàbí kẹ̀, kí ẹ gbà gbọ́ nítorí àwọn iṣẹ́ náà fúnra wọn.+
-