Jòhánù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìmọ́lẹ̀ tòótọ́ tó ń fún onírúurú èèyàn ní ìmọ́lẹ̀ máa tó wá sí ayé.+ Jòhánù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.” Jòhánù 9:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí mo bá ṣì wà ní ayé, èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.”+ Jòhánù 12:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Mo wá sínú ayé bí ìmọ́lẹ̀,+ kí gbogbo ẹni tó bá ń ní ìgbàgbọ́ nínú mi má bàa wà nínú òkùnkùn.+
8 12 Jésù tún sọ fún wọn pé: “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé.+ Ó dájú pé ẹnikẹ́ni tó bá ń tẹ̀ lé mi kò ní rìn nínú òkùnkùn, àmọ́ ó máa ní ìmọ́lẹ̀+ ìyè.”