Jòhánù 1:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ̀rí tí Jòhánù jẹ́ nìyí nígbà tí àwọn Júù rán àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì láti Jerúsálẹ́mù kí wọ́n lọ bi í pé: “Ta ni ọ́?”+ 20 Ó sọ òótọ́, kò sì sẹ́, ó ní: “Èmi kọ́ ni Kristi.”
19 Ẹ̀rí tí Jòhánù jẹ́ nìyí nígbà tí àwọn Júù rán àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì láti Jerúsálẹ́mù kí wọ́n lọ bi í pé: “Ta ni ọ́?”+ 20 Ó sọ òótọ́, kò sì sẹ́, ó ní: “Èmi kọ́ ni Kristi.”