Jòhánù 8:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ìsàlẹ̀ ni ẹ̀yin ti wá; èmi wá láti òkè.+ Inú ayé yìí lẹ ti wá; èmi ò wá látinú ayé yìí.
23 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ìsàlẹ̀ ni ẹ̀yin ti wá; èmi wá láti òkè.+ Inú ayé yìí lẹ ti wá; èmi ò wá látinú ayé yìí.