-
Jòhánù 8:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Mo ní ọ̀pọ̀ nǹkan tí mo fẹ́ sọ nípa yín, tí mo sì fẹ́ ṣèdájọ́ rẹ̀. Ní tòótọ́, olóòótọ́ ni Ẹni tó rán mi, àwọn ohun tí mo sì gbọ́ látọ̀dọ̀ rẹ̀ ni mò ń sọ nínú ayé.”+
-
-
Jòhánù 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mi ò pè yín ní ẹrú mọ́, torí pé ẹrú kì í mọ ohun tí ọ̀gá rẹ̀ ń ṣe. Àmọ́ mo pè yín ní ọ̀rẹ́, torí pé mo ti jẹ́ kí ẹ mọ gbogbo ohun tí mo gbọ́ látọ̀dọ̀ Baba mi.
-