Ìṣe 2:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Nítorí náà, àwọn tó fi ayọ̀ gba ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣe ìrìbọmi,+ ní ọjọ́ yẹn nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) èèyàn* ló dara pọ̀ mọ́ wọn.+ Ìṣe 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí náà, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń gbilẹ̀ nìṣó,+ iye àwọn ọmọ ẹ̀yìn sì ń pọ̀ sí i gidigidi+ ní Jerúsálẹ́mù; ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àlùfáà sì bẹ̀rẹ̀ sí í tẹ́wọ́ gba* ìgbàgbọ́ náà.+
41 Nítorí náà, àwọn tó fi ayọ̀ gba ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣe ìrìbọmi,+ ní ọjọ́ yẹn nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) èèyàn* ló dara pọ̀ mọ́ wọn.+
7 Nítorí náà, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ń gbilẹ̀ nìṣó,+ iye àwọn ọmọ ẹ̀yìn sì ń pọ̀ sí i gidigidi+ ní Jerúsálẹ́mù; ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àlùfáà sì bẹ̀rẹ̀ sí í tẹ́wọ́ gba* ìgbàgbọ́ náà.+