Ìṣe 8:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí àwọn àpọ́sítélì tó wà ní Jerúsálẹ́mù gbọ́ pé Samáríà ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,+ wọ́n rán Pétérù àti Jòhánù sí wọn;
14 Nígbà tí àwọn àpọ́sítélì tó wà ní Jerúsálẹ́mù gbọ́ pé Samáríà ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,+ wọ́n rán Pétérù àti Jòhánù sí wọn;