-
Ìṣe 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nípasẹ̀ orúkọ rẹ̀ àti nípa ìgbàgbọ́ tí a ní nínú orúkọ rẹ̀, ni ara ọkùnrin tí ẹ rí, tí ẹ sì mọ̀ yìí fi yá. Ìgbàgbọ́ tí a ní nípasẹ̀ rẹ̀ ló mú ara ọkùnrin yìí dá ṣáṣá níṣojú gbogbo yín.
-