Ìṣe 5:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Ananáyà pẹ̀lú Sàfírà ìyàwó rẹ̀ ta àwọn ohun ìní kan. 2 Àmọ́, ó yọ lára owó náà pa mọ́, ìyàwó rẹ̀ sì mọ̀ sí i, ó wá mú apá kan rẹ̀ wá, ó sì fi í sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì.+
5 Ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Ananáyà pẹ̀lú Sàfírà ìyàwó rẹ̀ ta àwọn ohun ìní kan. 2 Àmọ́, ó yọ lára owó náà pa mọ́, ìyàwó rẹ̀ sì mọ̀ sí i, ó wá mú apá kan rẹ̀ wá, ó sì fi í sílẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì.+