Ìṣe 11:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìròyìn nípa wọn dé ìjọ tó wà ní Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì rán Bánábà+ lọ títí dé Áńtíókù. Ìṣe 12:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ti Bánábà+ àti Sọ́ọ̀lù, lẹ́yìn tí wọ́n ti parí gbogbo iṣẹ́ ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe ní Jerúsálẹ́mù,+ wọ́n pa dà, wọ́n sì mú Jòhánù+ tí wọ́n tún ń pè ní Máàkù dání.
25 Ní ti Bánábà+ àti Sọ́ọ̀lù, lẹ́yìn tí wọ́n ti parí gbogbo iṣẹ́ ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe ní Jerúsálẹ́mù,+ wọ́n pa dà, wọ́n sì mú Jòhánù+ tí wọ́n tún ń pè ní Máàkù dání.