Ìṣe 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nígbà tí wọ́n rawọ́ ẹ̀bẹ̀* tán, ibi tí wọ́n kóra jọ sí mì tìtì, gbogbo wọn lẹ́nì kọ̀ọ̀kan kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì ń fi ìgboyà sọ̀rọ̀ Ọlọ́run.+
31 Nígbà tí wọ́n rawọ́ ẹ̀bẹ̀* tán, ibi tí wọ́n kóra jọ sí mì tìtì, gbogbo wọn lẹ́nì kọ̀ọ̀kan kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì ń fi ìgboyà sọ̀rọ̀ Ọlọ́run.+