Jẹ́nẹ́sísì 21:1-3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà rántí Sérà gẹ́gẹ́ bí ó ṣe sọ, Jèhófà sì ṣe ohun tó ṣèlérí+ fún Sérà. 2 Sérà lóyún,+ ó sì bí ọmọkùnrin kan fún Ábúráhámù ní ọjọ́ ogbó rẹ̀ ní àkókò tí Ọlọ́run ṣèlérí fún un.+ 3 Ábúráhámù pe orúkọ ọmọ tuntun tí Sérà bí fún un ní Ísákì.+
21 Jèhófà rántí Sérà gẹ́gẹ́ bí ó ṣe sọ, Jèhófà sì ṣe ohun tó ṣèlérí+ fún Sérà. 2 Sérà lóyún,+ ó sì bí ọmọkùnrin kan fún Ábúráhámù ní ọjọ́ ogbó rẹ̀ ní àkókò tí Ọlọ́run ṣèlérí fún un.+ 3 Ábúráhámù pe orúkọ ọmọ tuntun tí Sérà bí fún un ní Ísákì.+