Jẹ́nẹ́sísì 46:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọmọ méjì* ni Jósẹ́fù bí ní Íjíbítì. Gbogbo ará* ilé Jékọ́bù tó wá sí Íjíbítì jẹ́ àádọ́rin (70).+ Diutarónómì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àwọn baba ńlá rẹ àti ìdílé wọn jẹ́ àádọ́rin (70) èèyàn* nígbà tí wọ́n lọ sí Íjíbítì,+ àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti mú kí o pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+
22 Àwọn baba ńlá rẹ àti ìdílé wọn jẹ́ àádọ́rin (70) èèyàn* nígbà tí wọ́n lọ sí Íjíbítì,+ àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti mú kí o pọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run.+