-
Ẹ́kísódù 11:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhófà sì jẹ́ kí àwọn èèyàn náà rí ojúure àwọn ará Íjíbítì. Mósè fúnra rẹ̀ ti wá di ẹni ńlá nílẹ̀ Íjíbítì lójú àwọn ìránṣẹ́ Fáráò àti àwọn èèyàn náà.
-