-
Émọ́sì 5:25-27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ǹjẹ́ ẹ mú ẹbọ àti ọrẹ wá fún mi
Ní gbogbo ogójì (40) ọdún tí ẹ fi wà ní aginjù, ilé Ísírẹ́lì?+
-
25 Ǹjẹ́ ẹ mú ẹbọ àti ọrẹ wá fún mi
Ní gbogbo ogójì (40) ọdún tí ẹ fi wà ní aginjù, ilé Ísírẹ́lì?+