38 Ẹni yìí wà lára ìjọ tó wà ní aginjù, ó wà pẹ̀lú áńgẹ́lì+ tó bá a sọ̀rọ̀+ lórí Òkè Sínáì pẹ̀lú àwọn baba ńlá wa, ó sì gba àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde mímọ́ tó jẹ́ ààyè láti fún wa.+
19 Ti Òfin ti wá jẹ́? A fi kún un láti mú kí àwọn àṣìṣe fara hàn kedere,+ títí ọmọ* tí a ṣe ìlérí náà fún á fi dé;+ a sì fi í rán àwọn áńgẹ́lì + nípasẹ̀ alárinà kan.+