Mátíù 26:59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Àwọn olórí àlùfáà àti gbogbo Sàhẹ́ndìrìn ń wá ẹ̀rí èké tí wọ́n máa fi mú Jésù kí wọ́n lè pa á.+