Ìṣe 9:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, Ananáyà lọ, ó sì wọ ilé náà, ó gbé ọwọ́ lé e, ó sì sọ pé: “Sọ́ọ̀lù, arákùnrin, Jésù Olúwa tó fara hàn ọ́ lójú ọ̀nà tí ò ń gbà bọ̀ ló rán mi kí o lè tún máa ríran, kí o sì kún fún ẹ̀mí mímọ́.”+
17 Nítorí náà, Ananáyà lọ, ó sì wọ ilé náà, ó gbé ọwọ́ lé e, ó sì sọ pé: “Sọ́ọ̀lù, arákùnrin, Jésù Olúwa tó fara hàn ọ́ lójú ọ̀nà tí ò ń gbà bọ̀ ló rán mi kí o lè tún máa ríran, kí o sì kún fún ẹ̀mí mímọ́.”+