-
Lúùkù 24:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Bó ṣe ń súre fún wọn, a mú un kúrò lọ́dọ̀ wọn lọ sí ọ̀run.+
-
-
Ìṣe 1:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Lẹ́yìn tó ti sọ àwọn nǹkan yìí, bí wọ́n ṣe ń wò ó, a gbé e sókè, àwọsánmà sì gbà á lọ mọ́ wọn lójú.+
-