-
Ìṣe 26:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “Nítorí náà, Ọba Ágírípà, mi ò ṣàìgbọràn sí ìran àtọ̀runwá náà, 20 àmọ́ mo jẹ́ iṣẹ́ náà fún àwọn tó wà ní Damásíkù+ lákọ̀ọ́kọ́, lẹ́yìn náà fún àwọn tó wà ní Jerúsálẹ́mù + àti fún gbogbo ilẹ̀ Jùdíà àti fún àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú, pé kí wọ́n ronú pìwà dà, kí wọ́n sì yíjú sí Ọlọ́run nípa ṣíṣe àwọn iṣẹ́ tó fi ìrònúpìwàdà hàn.+
-