Ìṣe 11:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nítorí náà, ó lọ sí Tásù láti wá Sọ́ọ̀lù kàn.+ Gálátíà 1:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn ìyẹn, mo lọ sí agbègbè Síríà àti ti Sìlíṣíà.+