-
Ìṣe 4:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 tó bá jẹ́ pé lórí oore tí a ṣe fún ọkùnrin tó yarọ + ni ẹ ṣe ń wádìí lónìí yìí, tí ẹ sì fẹ́ mọ ẹni tó mú ọkùnrin yìí lára dá, 10 kí gbogbo yín àti gbogbo èèyàn Ísírẹ́lì yáa mọ̀ pé ní orúkọ Jésù Kristi ará Násárẹ́tì,+ ẹni tí ẹ kàn mọ́gi,*+ àmọ́ tí Ọlọ́run gbé dìde kúrò nínú ikú,+ ni ọkùnrin yìí fi dúró níbí pẹ̀lú ara yíyá gágá níwájú yín.
-