-
Lúùkù 8:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Nígbà tó dé ilé náà, kò jẹ́ kí ẹnì kankan bá òun wọlé àfi Pétérù, Jòhánù, Jémíìsì pẹ̀lú bàbá àti ìyá ọmọ náà.